Oriki Ilu Iseyin Omo Ebedi Moko - History & Culture
Welcome, Guest: Join Nigeria Student Forum / Login / Trending Now / Recent Topics

Stats: 25,323 Members, 79,311 Topics, 16,289 Comments. Date: Jun 3 2020, 1:34 pm

SPECIAL: Gain Admission Into 200 Level To Study In Any University Via IJMB | CAMBRIDGE | JUPEB | NO JAMB | LOW FEES | Call 07063085343, 08086347092 To Register!
NSF Banner Ads NSF Banner Ads NSF Banner Ads
Oriki Ilu Iseyin Omo Ebedi Moko. by jejelawlar (m): 1:58am on August 29
Jejelola Opeyemi
Lautech
Slt
Graduate, Nigeria.
Iseyin oro, Omo ebedi moko.
Omo ase tin mumi to dara.
Ilu eye kiki egan, kiki aponle.
Nibi oju ti n buni to jenu lo.
Bere ki o to WO
Nibi ti ewe
Gbe n je ariyeke.
To popo o n je belewo.
Ti igi oko n je oluwanran.
Se bi nibe lagbado ojo, ti n je topabodi.
Eni ba fe aso atata
Ile yoruba.
Eni ko kori si ilu-iseyin
Nibi ti won ti n hun gidi ninu aso.
Eni ba feran ija.
Ko kori sodo asabari ni saki.
Eni ba fe tare ko wa si ile ebedi moko.
Bi a ba se gege ote.
Ka mu ta seyin kuro.
To ba dojo are
Ka ran ni somo ebedi- moko.
Agbo gambari.
Agbo sokoto.
Agbo 'lorin
Agbo Oyo
Agbo 'badan pelu.
Sun gbon ao gbo ohun ti ilu mokin wi.
Awa lomo oro to n Jo.
Awa lomo oro to n yo.
Awa lomo oro ti n kun yunmuyunmu Lori oparun.
Ogun kan ko ja
Ko ja ilu iseyin
Lati ojo alaye ti daye.

Power by : Com.Lhml Jejelola Opeyemi[pdf][/pdf]

2 Likes

ope

Don't have an account? Use the form below to signup for a Nigeria Student Forum Account
E.g Seuncoded

I agree to the terms of service

Re: Oriki Ilu Iseyin Omo Ebedi Moko. by Seuncoded (m): 9:33am on August 29
Fadeyi Oluwaseun
Ladoke Akintola University Ogbomosho
B.tech Marketing Management
Graduate, Nigeria.
This is really interesting

2 Like

Viewing this topic:
2 guests viewing this topic
NSF Banner Ads NSF Banner Ads NSF Banner Ads
Download the Ngstudentforum app for Android Devices

Disclaimer: Every Nigeria Student Forum member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nigeria Student Forum.
- Copyright © 2016 - 2020. All rights reserved.